Threeco Ṣe Àlékún Ìranlọ́wọ́ Ìpolongo Ìbò Ẹgbẹ́ APC Ní Ìfọ̀ Pẹ̀lú Owó Àádọ́ta Mílíọ̀nù Náírà
Zainab Omowunmi Ni ipalẹmọ silẹ de eto idibo gbogbogboo ti yoo bẹrẹ laipẹ yii, Ọtunba Muraina Olatunji Banjoko ti…
Ka tete dena iwa ọdaran ṣe anfaani ju ka sọ pe a n gbogun ti iwa ọdaran lọ-Ganzallo
Zainab Omowunmi Ọga agba fajọ eleto abo nipinlẹ Ogun iyẹn Ogun StateCommunity, Social Orientation and Safety Corps, ti ọpọ…
Iriri aye ti jẹ ki n gbọn ju ọpọ awọn to kẹkọọ gboye lọ – MC Oluomo
Zainab Omowunmi Aarẹ ajọ awọn oṣiṣẹ ọkọ ni orile-ede Naijiria ìyẹn ajọ NURTW, Alhaji Musiliu Akinsanya ti ọpọlọpọ awọn…
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ Oriire rí ìtúsílẹ̀, ọwọ́ tẹ mẹ́jọ nínú àwọn ajínigbé naa
Zainab Omowunmi Idunnu subu lu ayo ni ọjọ Ẹti Jimọ oni yii nigbati awọn olukọ ati akẹẹkọ Ijọba ibilẹ…
Anfaani ti ko lẹgbẹ ni idasilẹ ọlọpaa ipinlẹ jẹ fun gbogbo orile-ede Naijiria – Dapo Abiodun
Zainab Omowunmi Gomina ipinlẹ Ogun, Omooba Dapo Abiodun to tun jẹ alaga gbogbo awọn gomina agbegbe Guusu ni orile-ede…
Mi O Fi Ẹgbẹ PDP Silẹ O, Ṣùgbọ́n Tinubu Lo Ni Ibo Mi Ni Ọdun 2027″ — Segun Showunmi
Zainab Omowunmi Gbajugbaja olori pataki ninu ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party (PDP) ati agbẹnusọ tẹlẹri fun Atiku Abubakar ,…
Ayẹyẹ fifi ẹṣin díje fẹ́ẹ́ wáyé n’Ìpínlẹ̀ Èkó
Ijọba Ipinlẹ Eko ti kede erongba lati bẹrẹ fifi ẹṣin dije gẹgẹ bi abala kan lati ṣe ifunlokun irinajo-afẹ, igbelarugẹ…
Ìjọba Èkó sayẹyẹ imọ̀ edá awọn odọ́ nibi idíje iṣẹ́ ọnà
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó ti tún fi ìlérí rẹ̀ múlẹ̀ pé yóò máa tẹ̀síwájú ní fífi agbára sí ìmọ̀ ẹ̀dá, ìṣẹ́…
Sanwó-Olú rọ àjọ SWDC láti fojúsun ìdàgbàsókè ẹkùn Ìwọ̀-Oòrùn
Gomina Ipinlẹ Eko, Babajide Sanwo-Olu, ti rọ awọn igbimọ ajọ idagbasoke ẹkun Iwọ Oorun lati ji giri si iṣẹ wọn,…
Ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ ni wọ́n n gbé kiri, ìpínlẹ̀ wa kọ́ ló ní àkọsílẹ̀ àkóràn HIV tó pọ̀jù lọ
Ijọba ipinlẹ Eko ti fọwọ odi gba ahesọ ọrọ to n lọ nigboro pe, ipinlẹ naa lo ni akọsilẹ akoran…










